Sáàmù 73:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bí ọ̀rọ̀ àwọn ẹni burúkú ṣe rí nìyí, àwọn tí gbogbo nǹkan dẹrùn fún.+ Wọ́n ń kó ọrọ̀ jọ ṣáá.+ Sáàmù 73:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ẹ wo bí wọ́n ti pa rẹ́ lójijì!+ Ẹ wo bí òpin ṣe dé bá wọn lójijì, tí wọ́n sì pa run!