Òwe 16:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Èèyàn lè ro bí ọ̀nà rẹ̀ ṣe máa rí lọ́kàn rẹ̀,Àmọ́ Jèhófà ló ń darí ìṣísẹ̀ rẹ̀.+