Sáàmù 52:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ìdí nìyẹn tí Ọlọ́run yóò fi mú ọ balẹ̀ láìtún gbérí mọ́;+Yóò gbá ọ mú, yóò sì fà ọ́ kúrò nínú àgọ́ rẹ;+Yóò fà ọ́ tu kúrò ní ilẹ̀ alààyè.+ (Sélà) 6 Àwọn olódodo á rí i, ẹnu á yà wọ́n,+Wọ́n á sì fi í rẹ́rìn-ín.+
5 Ìdí nìyẹn tí Ọlọ́run yóò fi mú ọ balẹ̀ láìtún gbérí mọ́;+Yóò gbá ọ mú, yóò sì fà ọ́ kúrò nínú àgọ́ rẹ;+Yóò fà ọ́ tu kúrò ní ilẹ̀ alààyè.+ (Sélà) 6 Àwọn olódodo á rí i, ẹnu á yà wọ́n,+Wọ́n á sì fi í rẹ́rìn-ín.+