Sáàmù 32:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Tọ̀sántòru ni ọwọ́* rẹ le lára mi.+ Okun mi ti gbẹ* bí omi ṣe ń gbẹ nígbà ẹ̀ẹ̀rùn. (Sélà)