Jẹ́nẹ́sísì 18:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ó dájú pé o ò ní hùwà báyìí, pé kí o pa olódodo pẹ̀lú ẹni burúkú, tó fi jẹ́ pé ohun kan náà+ ló máa ṣẹlẹ̀ sí olódodo àti ẹni burúkú! Ó dájú pé o ò ní ṣe bẹ́ẹ̀.+ Ṣé Onídàájọ́ gbogbo ayé kò ní ṣe ohun tó tọ́ ni?”+ Sáàmù 9:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ Jèhófà wà lórí ìtẹ́ títí láé;+Ó ti fìdí ìtẹ́ rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in láti máa ṣe ìdájọ́ òdodo.+ 8 Yóò fi òdodo ṣe ìdájọ́ ilẹ̀ ayé tí à ń gbé;*+Yóò dá ẹjọ́ òdodo fún àwọn orílẹ̀-èdè.+
25 Ó dájú pé o ò ní hùwà báyìí, pé kí o pa olódodo pẹ̀lú ẹni burúkú, tó fi jẹ́ pé ohun kan náà+ ló máa ṣẹlẹ̀ sí olódodo àti ẹni burúkú! Ó dájú pé o ò ní ṣe bẹ́ẹ̀.+ Ṣé Onídàájọ́ gbogbo ayé kò ní ṣe ohun tó tọ́ ni?”+
7 Àmọ́ Jèhófà wà lórí ìtẹ́ títí láé;+Ó ti fìdí ìtẹ́ rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in láti máa ṣe ìdájọ́ òdodo.+ 8 Yóò fi òdodo ṣe ìdájọ́ ilẹ̀ ayé tí à ń gbé;*+Yóò dá ẹjọ́ òdodo fún àwọn orílẹ̀-èdè.+