Sáàmù 6:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìbànújẹ́ ti sọ ojú mi di bàìbàì;+Ojú mi ti ṣú* nítorí gbogbo àwọn tó ń halẹ̀ mọ́ mi.