2 Sámúẹ́lì 16:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bóyá Jèhófà máa rí ìpọ́njú mi,+ tí Jèhófà yóò sì fi ire san án pa dà fún mi dípò èpè tí ó ń ṣẹ́ lé mi lórí lónìí yìí.”+ Sáàmù 123:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Bí ojú àwọn ìránṣẹ́ ṣe ń wo ọwọ́ ọ̀gá wọnÀti bí ojú ìránṣẹ́bìnrin ṣe ń wo ọwọ́ ọ̀gá rẹ̀ obìnrin,Bẹ́ẹ̀ ni ojú wa ń wo Jèhófà Ọlọ́run wa,+Títí á fi ṣojú rere sí wa.+
12 Bóyá Jèhófà máa rí ìpọ́njú mi,+ tí Jèhófà yóò sì fi ire san án pa dà fún mi dípò èpè tí ó ń ṣẹ́ lé mi lórí lónìí yìí.”+
2 Bí ojú àwọn ìránṣẹ́ ṣe ń wo ọwọ́ ọ̀gá wọnÀti bí ojú ìránṣẹ́bìnrin ṣe ń wo ọwọ́ ọ̀gá rẹ̀ obìnrin,Bẹ́ẹ̀ ni ojú wa ń wo Jèhófà Ọlọ́run wa,+Títí á fi ṣojú rere sí wa.+