Sáàmù 51:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí mo mọ àwọn àṣìṣe mi dáadáa,Ẹ̀ṣẹ̀ mi sì wà níwájú mi* nígbà gbogbo.+