Sáàmù 22:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Má jìnnà sí mi, torí wàhálà ti dé tán+Mi ò sì ní olùrànlọ́wọ́+ míì. Sáàmù 35:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 O ti rí èyí ná, Jèhófà. Má ṣe dákẹ́.+ Jèhófà, má jìnnà sí mi.+