Hébérù 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 bó ṣe sọ pé: “Màá sọ orúkọ rẹ fún àwọn arákùnrin mi; màá sì fi orin yìn ọ́ láàárín ìjọ.”+