-
Sáàmù 35:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Àmọ́ kí àwọn tí inú wọn ń dùn sí òdodo mi kígbe ayọ̀;
Kí wọ́n máa sọ nígbà gbogbo pé:
“Kí a gbé Jèhófà ga, ẹni tí inú rẹ̀ ń dùn sí àlàáfíà ìránṣẹ́ rẹ̀.”+
-