Jẹ́nẹ́sísì 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Lẹ́yìn èyí, Jèhófà sọ fún Ábúrámù nínú ìran pé: “Ábúrámù, má bẹ̀rù.+ Apata ni mo jẹ́ fún ọ.+ Èrè rẹ yóò pọ̀ gan-an.”+ Òwe 30:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Gbogbo ọ̀rọ̀ Ọlọ́run mọ́.+ Ó* jẹ́ apata fún àwọn tó ń wá ààbò lọ́dọ̀ rẹ̀.+
15 Lẹ́yìn èyí, Jèhófà sọ fún Ábúrámù nínú ìran pé: “Ábúrámù, má bẹ̀rù.+ Apata ni mo jẹ́ fún ọ.+ Èrè rẹ yóò pọ̀ gan-an.”+