Òwe 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nítorí àwọn adúróṣinṣin ló máa gbé ní ayé,Àwọn aláìlẹ́bi* ló sì máa ṣẹ́ kù sínú rẹ̀.+