Sáàmù 55:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọkàn mi ń jẹ̀rora nínú mi,+Jìnnìjìnnì ikú sì bò mí.+ Máàkù 14:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ó sọ fún wọn pé: “Ẹ̀dùn ọkàn bá mi* gan-an,+ àní títí dé ikú. Ẹ dúró síbí, kí ẹ sì máa ṣọ́nà.”+