Jónà 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà, ìwọ ni Ẹni tí mo rántí nígbà tí ẹ̀mí* mi fẹ́rẹ̀ẹ́ bọ́.+ Ìgbà yẹn ni mo gbàdúrà sí ọ, àdúrà mi sì wọnú tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ.+
7 Jèhófà, ìwọ ni Ẹni tí mo rántí nígbà tí ẹ̀mí* mi fẹ́rẹ̀ẹ́ bọ́.+ Ìgbà yẹn ni mo gbàdúrà sí ọ, àdúrà mi sì wọnú tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ.+