Sáàmù 42:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Màá sọ fún Ọlọ́run, àpáta mi pé: “Kí nìdí tí o fi gbàgbé mi?+ Kí nìdí tí mo fi ń rìn kiri nínú ìbànújẹ́ nítorí pé ọ̀tá mi ń ni mí lára?”+
9 Màá sọ fún Ọlọ́run, àpáta mi pé: “Kí nìdí tí o fi gbàgbé mi?+ Kí nìdí tí mo fi ń rìn kiri nínú ìbànújẹ́ nítorí pé ọ̀tá mi ń ni mí lára?”+