-
Diutarónómì 4:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Ó lé àwọn orílẹ̀-èdè tó tóbi, tí wọ́n sì lágbára jù ọ́ lọ kúrò níwájú rẹ, kó lè mú ọ wọlé, kó sì fún ọ ní ilẹ̀ wọn kí o lè jogún rẹ̀, bó ṣe rí lónìí.+
-