1 Sámúẹ́lì 12:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Jèhófà kò ní kọ àwọn èèyàn rẹ̀ sílẹ̀+ nítorí orúkọ ńlá rẹ̀+ àti nítorí pé Jèhófà ti pinnu láti fi yín ṣe èèyàn rẹ̀.+
22 Jèhófà kò ní kọ àwọn èèyàn rẹ̀ sílẹ̀+ nítorí orúkọ ńlá rẹ̀+ àti nítorí pé Jèhófà ti pinnu láti fi yín ṣe èèyàn rẹ̀.+