Jóṣúà 24:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “‘Mo mú yín wá sí ilẹ̀ àwọn Ámórì tí wọ́n ń gbé ní òdìkejì* Jọ́dánì, wọ́n sì bá yín jà.+ Àmọ́ mo fi wọ́n lé yín lọ́wọ́, kí ẹ lè gba ilẹ̀ wọn, mo sì pa wọ́n run kúrò níwájú yín.+
8 “‘Mo mú yín wá sí ilẹ̀ àwọn Ámórì tí wọ́n ń gbé ní òdìkejì* Jọ́dánì, wọ́n sì bá yín jà.+ Àmọ́ mo fi wọ́n lé yín lọ́wọ́, kí ẹ lè gba ilẹ̀ wọn, mo sì pa wọ́n run kúrò níwájú yín.+