Diutarónómì 28:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 O máa di ohun tó ń dẹ́rù bani, ẹni ẹ̀gàn* àti ẹni ẹ̀sín láàárín gbogbo àwọn tí Jèhófà bá lé ọ lọ bá.+ 2 Kíróníkà 7:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 ńṣe ni màá fa Ísírẹ́lì tu lórí ilẹ̀ mi tí mo fún wọn,+ màá gbé ilé yìí tí mo yà sí mímọ́ fún orúkọ mi sọ nù kúrò níwájú mi, màá sọ ọ́ di ohun ẹ̀gàn* àti ohun ẹ̀sín láàárín gbogbo èèyàn.+
37 O máa di ohun tó ń dẹ́rù bani, ẹni ẹ̀gàn* àti ẹni ẹ̀sín láàárín gbogbo àwọn tí Jèhófà bá lé ọ lọ bá.+
20 ńṣe ni màá fa Ísírẹ́lì tu lórí ilẹ̀ mi tí mo fún wọn,+ màá gbé ilé yìí tí mo yà sí mímọ́ fún orúkọ mi sọ nù kúrò níwájú mi, màá sọ ọ́ di ohun ẹ̀gàn* àti ohun ẹ̀sín láàárín gbogbo èèyàn.+