-
Diutarónómì 32:42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
42 Màá mú kí ọfà mi mu ẹ̀jẹ̀ yó,
Idà mi á sì jẹ ẹran,
Pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ àwọn tí a pa àti àwọn ẹrú,
Pẹ̀lú orí àwọn aṣáájú ọ̀tá.’
-
42 Màá mú kí ọfà mi mu ẹ̀jẹ̀ yó,
Idà mi á sì jẹ ẹran,
Pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ àwọn tí a pa àti àwọn ẹrú,
Pẹ̀lú orí àwọn aṣáájú ọ̀tá.’