Sáàmù 33:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 À* ń dúró de Jèhófà. Òun ni olùrànlọ́wọ́ wa àti apata wa.+