Sáàmù 89:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Màá fìdí àwọn ọmọ* rẹ̀ múlẹ̀ títí láé,Màá sì mú kí ìtẹ́ rẹ̀ wà títí lọ bí ọ̀run.+ Sáàmù 89:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Àwọn ọmọ* rẹ̀ yóò wà títí láé;+Ìtẹ́ rẹ̀ yóò wà títí lọ bí oòrùn níwájú mi.+