Mátíù 7:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àmọ́, màá sọ fún wọn pé: ‘Mi ò mọ̀ yín rí! Ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi, ẹ̀yin arúfin!’+