Àìsáyà 13:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Màá mú kí ẹni kíkú ṣọ̀wọ́n ju wúrà tí wọ́n yọ́ mọ́,+Màá sì mú kí àwọn èèyàn ṣọ̀wọ́n ju wúrà Ófírì.+
12 Màá mú kí ẹni kíkú ṣọ̀wọ́n ju wúrà tí wọ́n yọ́ mọ́,+Màá sì mú kí àwọn èèyàn ṣọ̀wọ́n ju wúrà Ófírì.+