Àìsáyà 54:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn òkè ńlá lè ṣí kúrò,Àwọn òkè kéékèèké sì lè mì tìtì,Àmọ́ ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ ò ní kúrò lọ́dọ̀ rẹ,+Májẹ̀mú àlàáfíà mi ò sì ní mì,”+ ni Jèhófà, Ẹni tó ń ṣàánú rẹ wí.+
10 Àwọn òkè ńlá lè ṣí kúrò,Àwọn òkè kéékèèké sì lè mì tìtì,Àmọ́ ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ ò ní kúrò lọ́dọ̀ rẹ,+Májẹ̀mú àlàáfíà mi ò sì ní mì,”+ ni Jèhófà, Ẹni tó ń ṣàánú rẹ wí.+