Jóṣúà 2:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Wọ́n sọ fún Jóṣúà pé: “Jèhófà ti fi gbogbo ilẹ̀ náà lé wa lọ́wọ́.+ Kódà, ọkàn gbogbo àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà ti domi nítorí wa.”+
24 Wọ́n sọ fún Jóṣúà pé: “Jèhófà ti fi gbogbo ilẹ̀ náà lé wa lọ́wọ́.+ Kódà, ọkàn gbogbo àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà ti domi nítorí wa.”+