Àìsáyà 11:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọn ò ní fa ìpalára kankan,+Tàbí ìparun kankan ní gbogbo òkè mímọ́ mi,+Torí ó dájú pé ìmọ̀ Jèhófà máa bo ayé,Bí omi ṣe ń bo òkun.+ Míkà 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó máa ṣe ìdájọ́ láàárín ọ̀pọ̀ èèyàn,+Ó sì máa yanjú* ọ̀rọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè alágbára tí ọ̀nà wọn jìn. Wọ́n máa fi idà wọn rọ ohun ìtúlẹ̀,Wọ́n sì máa fi ọ̀kọ̀ wọn rọ ohun ìrẹ́wọ́ ọ̀gbìn.+ Àwọn orílẹ̀-èdè kò ní yọ idà sí ara wọn mọ́,Wọn ò sì ní kọ́ṣẹ́ ogun mọ́.+
9 Wọn ò ní fa ìpalára kankan,+Tàbí ìparun kankan ní gbogbo òkè mímọ́ mi,+Torí ó dájú pé ìmọ̀ Jèhófà máa bo ayé,Bí omi ṣe ń bo òkun.+
3 Ó máa ṣe ìdájọ́ láàárín ọ̀pọ̀ èèyàn,+Ó sì máa yanjú* ọ̀rọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè alágbára tí ọ̀nà wọn jìn. Wọ́n máa fi idà wọn rọ ohun ìtúlẹ̀,Wọ́n sì máa fi ọ̀kọ̀ wọn rọ ohun ìrẹ́wọ́ ọ̀gbìn.+ Àwọn orílẹ̀-èdè kò ní yọ idà sí ara wọn mọ́,Wọn ò sì ní kọ́ṣẹ́ ogun mọ́.+