2 Kíróníkà 20:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kò ní sídìí fún yín láti ja ogun yìí. Ẹ dúró sáyè yín, ẹ dúró jẹ́ẹ́,+ kí ẹ sì rí ìgbàlà Jèhófà lórí yín.*+ Ìwọ Júdà àti Jerúsálẹ́mù, ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì jáyà.+ Ní ọ̀la, ẹ jáde sí wọn, Jèhófà á sì wà pẹ̀lú yín.’”+
17 Kò ní sídìí fún yín láti ja ogun yìí. Ẹ dúró sáyè yín, ẹ dúró jẹ́ẹ́,+ kí ẹ sì rí ìgbàlà Jèhófà lórí yín.*+ Ìwọ Júdà àti Jerúsálẹ́mù, ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì jáyà.+ Ní ọ̀la, ẹ jáde sí wọn, Jèhófà á sì wà pẹ̀lú yín.’”+