Diutarónómì 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà Ọlọ́run yín sì ti yàn yín kí ẹ lè di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,* nínú gbogbo èèyàn tó wà láyé.+ Málákì 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà sọ pé, “Mo ti fi hàn pé mo nífẹ̀ẹ́ yín.”+ Àmọ́, ẹ sọ pé: “Kí lo ṣe tó fi hàn pé o nífẹ̀ẹ́ wa?” Jèhófà sọ pé, “Ṣebí ọmọ ìyá ni Jékọ́bù àti Ísọ̀?+ Àmọ́ mo nífẹ̀ẹ́ Jékọ́bù,
6 Torí èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà Ọlọ́run yín sì ti yàn yín kí ẹ lè di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,* nínú gbogbo èèyàn tó wà láyé.+
2 Jèhófà sọ pé, “Mo ti fi hàn pé mo nífẹ̀ẹ́ yín.”+ Àmọ́, ẹ sọ pé: “Kí lo ṣe tó fi hàn pé o nífẹ̀ẹ́ wa?” Jèhófà sọ pé, “Ṣebí ọmọ ìyá ni Jékọ́bù àti Ísọ̀?+ Àmọ́ mo nífẹ̀ẹ́ Jékọ́bù,