Sáàmù 125:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 125 Àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà+Dà bí Òkè Síónì, tí kò ṣeé mì,Àmọ́ tí ó wà títí láé.+