-
Sáàmù 87:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Wọ́n á sọ nípa Síónì pé:
“Inú rẹ̀ ni a ti bí wọn lẹ́nì kọ̀ọ̀kan.”
Ẹni Gíga Jù Lọ yóò sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ ṣinṣin.
-
-
Míkà 4:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Máa fìdí múlẹ̀ gbọn-in sórí àwọn òkè,
A sì máa gbé e ga ju àwọn òkè kéékèèké lọ,
Àwọn èèyàn á sì máa rọ́ lọ síbẹ̀.+
-