Sáàmù 31:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àmọ́ Jèhófà, ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀ lé.+ Mo sọ pé: “Ìwọ ni Ọlọ́run mi.”+