Diutarónómì 8:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Tí o bá sọ lọ́kàn rẹ pé, ‘Agbára mi àti iṣẹ́ ọwọ́ mi ló sọ mí di ọlọ́rọ̀,’+ 18 rántí pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ ló fún ọ lágbára láti di ọlọ́rọ̀,+ kó lè mú májẹ̀mú rẹ̀ tó bá àwọn baba ńlá rẹ dá ṣẹ, bó ṣe rí lónìí.+ Òwe 18:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ohun ìní ọlọ́rọ̀ ni ìlú olódi rẹ̀;Lọ́kàn rẹ̀, ó dà bí ògiri tó ń dáàbò boni.+
17 Tí o bá sọ lọ́kàn rẹ pé, ‘Agbára mi àti iṣẹ́ ọwọ́ mi ló sọ mí di ọlọ́rọ̀,’+ 18 rántí pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ ló fún ọ lágbára láti di ọlọ́rọ̀,+ kó lè mú májẹ̀mú rẹ̀ tó bá àwọn baba ńlá rẹ dá ṣẹ, bó ṣe rí lónìí.+