Òwe 11:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọrọ̀* kò ní ṣeni láǹfààní ní ọjọ́ ìbínú ńlá,+Àmọ́ òdodo ló ń gbani lọ́wọ́ ikú.+ Mátíù 16:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Lóòótọ́, àǹfààní wo ni èèyàn máa rí tó bá jèrè gbogbo ayé àmọ́ tó pàdánù ẹ̀mí* rẹ̀?+ Àbí kí ni èèyàn máa fi dípò ẹ̀mí* rẹ̀?+
26 Lóòótọ́, àǹfààní wo ni èèyàn máa rí tó bá jèrè gbogbo ayé àmọ́ tó pàdánù ẹ̀mí* rẹ̀?+ Àbí kí ni èèyàn máa fi dípò ẹ̀mí* rẹ̀?+