16 Nítorí a kì í rántí ọlọ́gbọ́n tàbí òmùgọ̀ títí lọ.+ Bó pẹ́ bó yá, a ò ní rántí ẹnikẹ́ni mọ́. Báwo sì ni ọlọ́gbọ́n ṣe máa kú? Á kú pẹ̀lú àwọn òmùgọ̀.+
12 Ìdí nìyẹn tó fi jẹ́ pé, bí ẹ̀ṣẹ̀ ṣe tipasẹ̀ ẹnì kan wọ ayé, tí ikú sì wá nípasẹ̀ ẹ̀ṣẹ̀,+ bẹ́ẹ̀ ni ikú ṣe tàn dé ọ̀dọ̀ gbogbo èèyàn torí pé gbogbo wọn ti dẹ́ṣẹ̀+—.