-
Málákì 4:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé: “Ẹ ó tẹ àwọn ẹni burúkú mọ́lẹ̀, torí wọ́n á dà bí eruku lábẹ́ ẹsẹ̀ yín, ní ọjọ́ tí mo bá ṣe ohun tí mo sọ.”
-