Sáàmù 39:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 O fi ìyà tọ́ èèyàn sọ́nà nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀;+O run nǹkan tó kà sí iyebíye bí ìgbà tí òólá* bá jẹ nǹkan. Dájúdájú, èémí lásán ni ọmọ èèyàn.+ (Sélà)
11 O fi ìyà tọ́ èèyàn sọ́nà nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀;+O run nǹkan tó kà sí iyebíye bí ìgbà tí òólá* bá jẹ nǹkan. Dájúdájú, èémí lásán ni ọmọ èèyàn.+ (Sélà)