Jóòbù 24:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Bí ọ̀gbẹlẹ̀ àti ooru ṣe ń mú kí yìnyín yọ́ kó sì gbẹ,Bẹ́ẹ̀ ni Isà Òkú* ń mú àwọn tó dẹ́ṣẹ̀ lọ!+