-
Jeremáyà 9:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Kálukú ń rẹ́ ọmọnìkejì rẹ̀ jẹ,
Kò sì sí ẹni tó ń sọ òtítọ́.
Wọ́n ti kọ́ ahọ́n wọn láti máa pa irọ́.+
Wọ́n ṣe ohun tí kò tọ́ títí ó fi rẹ̀ wọ́n.
-