Jẹ́nẹ́sísì 39:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kò sẹ́ni tó tóbi jù mí lọ nínú ilé yìí, kò sì fawọ́ ohunkóhun sẹ́yìn fún mi àyàfi ìwọ, torí pé ìwọ ni ìyàwó rẹ̀. Ṣé ó wá yẹ kí n hùwà burúkú tó tó báyìí, kí n sì ṣẹ Ọlọ́run?”+ 2 Sámúẹ́lì 12:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Dáfídì wá sọ fún Nátánì pé: “Mo ti ṣẹ̀ sí Jèhófà.”+ Nátánì dá Dáfídì lóhùn pé: “Jèhófà, ní tirẹ̀ ti dárí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ jì ọ́.*+ O ò ní kú.+
9 Kò sẹ́ni tó tóbi jù mí lọ nínú ilé yìí, kò sì fawọ́ ohunkóhun sẹ́yìn fún mi àyàfi ìwọ, torí pé ìwọ ni ìyàwó rẹ̀. Ṣé ó wá yẹ kí n hùwà burúkú tó tó báyìí, kí n sì ṣẹ Ọlọ́run?”+
13 Dáfídì wá sọ fún Nátánì pé: “Mo ti ṣẹ̀ sí Jèhófà.”+ Nátánì dá Dáfídì lóhùn pé: “Jèhófà, ní tirẹ̀ ti dárí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ jì ọ́.*+ O ò ní kú.+