-
Jẹ́nẹ́sísì 24:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ló bá yára da omi tó wà nínú ìṣà rẹ̀ sínú ọpọ́n ìmumi, ó ń sáré lọ sáré bọ̀ síbi kànga náà kó lè fa omi, ó sì ń fa omi kó lè fún gbogbo àwọn ràkúnmí náà lómi.
-