Òwe 15:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ètè ọlọ́gbọ́n máa ń tan ìmọ̀ kálẹ̀,+Àmọ́ ọkàn àwọn òmùgọ̀ kì í ṣe bẹ́ẹ̀.+