Òwe 9:16, 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Kí ẹni tó bá jẹ́ aláìmọ̀kan wọlé síbí.” Ó sọ fún àwọn tí kò ní làákàyè* pé:+ 17 “Omi tí a jí gbé máa ń dùn,Oúnjẹ tí a sì jẹ ní ìkọ̀kọ̀ máa ń gbádùn mọ́ni.”+
16 “Kí ẹni tó bá jẹ́ aláìmọ̀kan wọlé síbí.” Ó sọ fún àwọn tí kò ní làákàyè* pé:+ 17 “Omi tí a jí gbé máa ń dùn,Oúnjẹ tí a sì jẹ ní ìkọ̀kọ̀ máa ń gbádùn mọ́ni.”+