Òwe 22:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Kòtò jíjìn ni ẹnu obìnrin oníwàkiwà.*+ Ẹni tí Jèhófà dá lẹ́bi yóò já sínú rẹ̀.