-
Ẹ́kísódù 22:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Tí ohun tó jí bá ṣì wà láàyè, tó sì wà lọ́dọ̀ rẹ̀, bóyá akọ màlúù, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tàbí àgùntàn, kó san án pa dà ní ìlọ́po méjì.