Ìsíkíẹ́lì 27:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Aṣọ ọ̀gbọ̀* aláràbarà láti Íjíbítì ni wọ́n fi ṣe ìgbòkun rẹ,Fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù àti òwú aláwọ̀ pọ́pù láti erékùṣù Élíṣáhì+ ni wọ́n fi ṣe ìbòrí ọkọ̀ rẹ.
7 Aṣọ ọ̀gbọ̀* aláràbarà láti Íjíbítì ni wọ́n fi ṣe ìgbòkun rẹ,Fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù àti òwú aláwọ̀ pọ́pù láti erékùṣù Élíṣáhì+ ni wọ́n fi ṣe ìbòrí ọkọ̀ rẹ.