Jẹ́nẹ́sísì 1:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ọlọ́run sì sọ pé: “Kí òfúrufú+ wà láàárín omi, kí omi sì pín sọ́tọ̀ọ̀tọ̀.”+ 7 Ọlọ́run wá ṣe òfúrufú, ó pààlà sáàárín omi tó wà lókè òfúrufú náà àti omi tó wà ní ìsàlẹ̀ rẹ̀.+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀. Jóòbù 26:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ó pààlà* sójú òfúrufú àti omi;+Ó fi ààlà sáàárín ìmọ́lẹ̀ àti òkùnkùn.
6 Ọlọ́run sì sọ pé: “Kí òfúrufú+ wà láàárín omi, kí omi sì pín sọ́tọ̀ọ̀tọ̀.”+ 7 Ọlọ́run wá ṣe òfúrufú, ó pààlà sáàárín omi tó wà lókè òfúrufú náà àti omi tó wà ní ìsàlẹ̀ rẹ̀.+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀.