Ẹ́kísódù 23:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Jèhófà Ọlọ́run yín ni ẹ gbọ́dọ̀ máa sìn,+ yóò sì bù kún oúnjẹ àti omi yín.+ Èmi yóò mú àìsàn kúrò láàárín yín.+ Òwe 28:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Olóòótọ́ èèyàn yóò gba ọ̀pọ̀ ìbùkún,+Àmọ́ ọwọ́ ẹni tó ń kánjú láti di olówó kò lè mọ́.+
25 Jèhófà Ọlọ́run yín ni ẹ gbọ́dọ̀ máa sìn,+ yóò sì bù kún oúnjẹ àti omi yín.+ Èmi yóò mú àìsàn kúrò láàárín yín.+