-
1 Tímótì 5:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Àwọn kan wà tí ẹ̀ṣẹ̀ wọn máa ń hàn sí ọ̀pọ̀ èèyàn, ó sì máa ń yọrí sí ìdájọ́ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, àmọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àwọn míì máa ń hàn síta nígbà tó bá yá.+
-